Oba onipokia ft Agaga – Yoruba ji masun


Download “OBA ONIPOKIA ft AGAGA – YORUBA JI MASUN” OBA-ONIPOKIA-ft-AGAGA-YORUBA-JI-MASUN.mp3 – Downloaded 342 times – 4 MB

Agaga season man aka Mr pupa in his new release title “YORUBA JI MASUN” the ever educative song which features a prominent king in the Yoruba land ONIPOKI of IPOKIA land.

“YORUBA JI MASUN” is an inspirational song that tends to gear the Yoruba race to wake from slumber. Lyrics below

Sebi ijo lara oba nigba ni lodi ijoba

Eyin oba wa sebeyin ni baba wa

Ema laju yin sile kajeji kogba ile wa

Kon ye pa awon eyan wa loju yin

Eje kase pada senu oba

Oleselu gbodo ma gbase lenu oba

Sebi yen non peni ijoba

Otipe ti Yoruba tin fenu se

Oya ekuro lenu ere

Lowoyi eduro dede

Ki tenant ma pada le onile

Listen Download & Share below

Stream Video below

3 Comments

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*